Amọ̀nà Fún Ìwé Mímọ́
-
Jésù Krístì Olúwa
Àwòrán láti ọwọ́ Heinrich Hofmann
-
Wòlĩ Joseph Smith
Àwòrán láti ọwọ́ Alvin Gittins
-
Léhì ri Liahónà
Àwòrán láti ọwọ́ Arnold Friberg
-
Léhì àti àwọn ènìyàn rẹ dé Ilẹ̀ Ìlérí
Àwòrán láti ọwọ́ Arnold Friberg
-
Álmà rì awọn eniyan bọmi ninu Àwọn Omi Mọ́mọ́nì
Àwòrán láti ọwọ́ Arnold Friberg
-
Sámúẹ́lì ará Lámánì sọ-tẹ́lẹ̀
Àwòrán láti ọwọ́ Arnold Friberg
-
Jésù Krístì bẹ Ilẹ̀ Amẹ́ríkà wò
Àwòrán láti ọwọ́ John Scott
-
Mórónì bò ìwé ìrántí àwọn ará Nífáì mọ́lẹ̀
Àwòrán láti ọwọ́ Tom Lovell