Jésù Krístì

Sacrament Prayers

  • Àwọn Àkọọ́nú

  • Ìbùkún Lórí Búrẹ́dì

  • Ìbùkún Lóri Omi

Sacrament Prayers


Sacrament Prayers

  • Ìbùkún Lórí Búrẹ́dì

    A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé, àwá bẽrè lọ́wọ́ yín ní orúkọ Ọmọ yín, Jésù Krístì, pé kí ẹ bùkún kí ẹ sì yà búrẹ́dì yĩ sí mímọ́ fún ọkàn gbogbo àwọn tí ó jẹ́ alábãpín nínú rẹ̀; láti lè jẹ ní ìrántí ara ti Ọmọ yín, kí wọn ó sì jẹ̃rí sí yín, A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé, pé wọ́n ní ìfẹ́ láti gba orúkọ Ọmọ yín sórí wọn, wọ́n sì rántí rẹ̀ nígbàgbogbo, wọ́n sì npa òfin rẹ̀ mọ́ èyítí tí ó ti fi fún wọn, kí wọ́n ó lè ní Ẹ̀mí rẹ̀ pẹ̀lú wọn nígbàgbogbo. Àmín.


  • Ìbùkún Lóri Omi

    A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé, àwá bèrè lọ́wọ́ yin, ní orúkọ Ọmọ yín, Jésù Krístì, pé kí ẹ bùkún kí ẹ sì yà omi yĩ sí mímọ́ fún ọkàn gbogbo àwọn tí ó mu nínú rè, láti lè ṣe é ní ìrántí ẹ̀jẹ̀ Ọmọ yín, èyítí a ta sílẹ̀ fún wọn; láti lè jẹ̃rí sí yín, A! Ọlọ́run, Bàbá Ayérayé, pé wọ́n ńṣe ìrántí rẹ̀ nígbàgbogbo, kí wọ́n ó lè ní Ẹ̀mí rẹ̀ pẹ̀lú wọn. Àmín.