Oṣù Kẹrin 2022 Oúnjẹ Olúwa: Ọ̀nà Kan Láti Rántí OlùgbàlàÀwọn kókó ìlànà nípa oúnjẹ Oluwa. Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ Fún àwọn Ọ̀dọ́ Olùgbàlà Tó ŃjìyàGba àlàyé ṣókí nípa Isaiah 53:3-5, àsọtẹ́lẹ̀ kan nípá ìjìyà Jesu Kristi fún àwọn ẹṣẹ wa. Fríẹ́ndì Fún Àwọn ọmọde: Mose àti MánàKa ìtàn nípa bí Ọlọ́run ṣe pèsè mánà fún Mósè àti àwọn ọmọ Ísráẹ́lì.